1
ORIN DAFIDI 126:5
Yoruba Bible
YCE
Àwọn tí ń fọ́n irúgbìn pẹlu omi lójú, jẹ́ kí wọn kórè rẹ̀ tayọ̀tayọ̀.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 126:5
2
ORIN DAFIDI 126:6
Ẹni tí ń gbé irúgbìn lọ sí oko tẹkúntẹkún, yóo ru ìtí ọkà pada sílé tayọ̀tayọ̀.
Explore ORIN DAFIDI 126:6
3
ORIN DAFIDI 126:3
Lóòótọ́, OLUWA ṣe nǹkan ńlá fún wa, nítorí náà à ń yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 126:3